Deutarónómì 13:4 BMY

4 Olúwa Ọlọ́run yín ni kí ẹ tẹ̀lé, Òun ni kí ẹ bọlá fún, ẹ pa òfin rẹ̀ mọ́ kí ẹ sì gbọ́ tirẹ̀: ẹ sìn ín, kí ẹ sì dì í mú ṣinṣin.

Ka pipe ipin Deutarónómì 13

Wo Deutarónómì 13:4 ni o tọ