Deutarónómì 14:9 BMY

9 Nínú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ń gbé inú omi, ẹ lè jẹ èyíkéyí tí ó ní lẹbẹ àti ìpẹ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 14

Wo Deutarónómì 14:9 ni o tọ