Deutarónómì 15:12 BMY

12 Bí Hébérù ara yín kan, yálà ọkùnrin tàbí obìnrin bá ta ara rẹ̀ fún ọ, tí ó sì sìn ọ́ fún ọdún mẹ́fà. Ní ọdún kéje, jẹ́ kí ó di òmìnira.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:12 ni o tọ