Deutarónómì 15:11 BMY

11 A kò lè fẹ́ tálákà kù ní ilẹ̀ náà ní ìgbà gbogbo, mo pàṣẹ fún un yín láti lawọ́ sí àwọn arákùnrin yín, sí àwọn talákà àti sí àwọn aláìní, ní ilẹ̀ ẹ yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:11 ni o tọ