Deutarónómì 15:14 BMY

14 Fi tọkàntọkàn fún un láti inú agbo ewúrẹ́ rẹ, ilẹ̀ ìpakà rẹ, àti ibi ìfúntí rẹ. Fún un gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti bùkún fún ọ tó.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:14 ni o tọ