Deutarónómì 15:15 BMY

15 Ẹ rántí pé ẹ ti fi ìgbà kan jẹ́ ẹrú ní Éjíbítì, Olúwa Ọlọ́run yín sì rà yín padà, ìdí nìyí tí mo fi pa àṣẹ yìí fún un yín lónìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:15 ni o tọ