Deutarónómì 15:20 BMY

20 Ní ọdọọdún ni kí ìwọ àti ìdílé rẹ máa jẹ ẹ́ níwájú Olúwa Ọlọ́run yín níbi tí Òun yóò yàn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:20 ni o tọ