Deutarónómì 15:21 BMY

21 Bí ẹran ọ̀ṣìn kan bá ní àbùkù: bóyá ó yarọ, tàbí fọ́jú, tàbí tí ó ní èyíkèyìí àbùkù tó burú. Ẹ kò gbọdọ̀ fi rúbọ sí Olúwa Ọlọ́run yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:21 ni o tọ