Deutarónómì 15:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí yóò tọ́ sí nínú un yín, nítorí pé Ọlọ́run yín yóò bùkún un yín lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú ilẹ̀ náà tí ó ń mú un yín lọ láti gbà bí ìní yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:4 ni o tọ