Deutarónómì 15:5 BMY

5 Kìkì bí ẹ bá gbọ́ràn sí àṣẹ Olúwa Ọlọ́run yín tí ẹ sì kíyèsára láti máa rìn nínú gbogbo àṣẹ wọ̀nyí, tí èmi ń pa fún un yín lónìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:5 ni o tọ