Deutarónómì 16:19 BMY

19 Ẹ má ṣe yí ẹjọ́ po, ẹ kò sì gbọdọ̀ ṣe ojúṣàájú. Ẹ má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ nítorí pé àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ń fọ́ ojú ọlọgbọ́n, ó sì ń ba ọ̀rọ̀ òdodo jẹ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 16

Wo Deutarónómì 16:19 ni o tọ