Deutarónómì 16:20 BMY

20 Ẹ tẹ̀lé ìdájọ́ òtítọ́ àní ìdájọ́ òtítọ́ nìkan, kí ẹ báà lè gbé kí ẹ sì gba ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín ń fún un yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 16

Wo Deutarónómì 16:20 ni o tọ