Deutarónómì 17:1 BMY

1 Ẹ má ṣe fi màlúù tàbí àgùntàn tí ó ní àbùkù, tàbí àbàwọ́n rúbọ sí Olúwa Ọlọ́run yín, nítorí ìríra ni èyí yóò jẹ́ fún un.

Ka pipe ipin Deutarónómì 17

Wo Deutarónómì 17:1 ni o tọ