Deutarónómì 17:2 BMY

2 Bí ọkùnrin tàbí obìnrin kan tó ń gbé láàrin yín ní èyíkéyìí ìlú wọ̀n-ọn-nì, tí Olúwa fún un yín bá ń ṣe ibi ní ojú Olúwa Ọlọ́run yín, ní ríré májẹ̀mú rẹ̀ kọjá,

Ka pipe ipin Deutarónómì 17

Wo Deutarónómì 17:2 ni o tọ