Deutarónómì 18:5 BMY

5 Nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti yàn wọ́n àti àwọn ọmọ wọn láti inú gbogbo ẹ̀yà láti dúró àti láti ṣe ìránṣẹ́ ní orúkọ Olúwa títí láé.

Ka pipe ipin Deutarónómì 18

Wo Deutarónómì 18:5 ni o tọ