Deutarónómì 18:6 BMY

6 Tí ọmọ Léfì kan bá sì wá láti ibikíbi nínú àwọn ìlú u yín ní Ísírẹ́lì, níbi tí ó ń gbé ṣe àtìpó, tí ó sì wá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀ sí ibi tí Ọlọ́run yóò yàn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 18

Wo Deutarónómì 18:6 ni o tọ