Deutarónómì 19:11 BMY

11 Ṣùgbọ́n tí ọkùnrin kan bá kórìíra arákùnrin rẹ̀, tí ó sì lúgọ dè é, tí ó mú u tí o lù ú pa, tí ọkùnrin náà sì sálọ sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú wọ̀nyí,

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:11 ni o tọ