Deutarónómì 19:12 BMY

12 àwọn olórí ìlú rẹ yóò sì ránṣẹ́ pè é ìwọ, yóò sì mú un padà láti ìlú náà, wọn yóò sì fi í lé àwọn agbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ lọ́wọ́ kí ó lè kú.

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:12 ni o tọ