Deutarónómì 19:20 BMY

20 Àwọn ènìyàn tókù yóò gbọ́ nípa èyí, wọn yóò sì bẹ̀rù, kí irú nǹkan búburú bẹ́ẹ̀ máa tún sẹ̀ mọ́ láàrin yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:20 ni o tọ