Deutarónómì 2:22 BMY

22 Bákan náà ni Olúwa ṣe fún àwọn ọmọ Ísọ̀, tí wọ́n ń gbé ní Séírì, nígbà tí ó pa àwọn ará Hórì run níwájú wọn. Wọ́n lé wọn jáde wọ́n sì ń gbé ní ilẹ̀ wọn títí di òní.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:22 ni o tọ