Deutarónómì 2:23 BMY

23 Nípa ti àwọn ará Áfì, tí wọ́n ń gbé ní àwọn ìlú kéékèèkéé dé Gásà, àwọn ará Káfórì, tí wọ́n jáde láti Kírétè wá ni ó pa wọ́n run, wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn.)

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:23 ni o tọ