Deutarónómì 2:28 BMY

28 Ẹ ta oúnjẹ tí a ó jẹ àti omi tí a ó mu fún wa ní iye owó wọn. Kìkì kí ẹ sáà jẹ́ kí a rìn kọjá:

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:28 ni o tọ