Deutarónómì 2:29 BMY

29 gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Éṣáù tí ó ń gbé ní Séírì àti àwọn ará Móábù tí ó ń gbé ní Árì, ti gbà wá láàyè títí a fi la Jọ́dánì já dé ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run wa yóò fún wa.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:29 ni o tọ