Deutarónómì 21:20 BMY

20 Wọn yóò sì wí fún àwọn àgbààgbà pé, “Ọmọ wa yìí jẹ́ aláìgbọ́ràn àti ọlọ̀tẹ̀. Kò ní gbọ́rọ̀ sí wa. Ó jẹ́ oníwà búburú àti ọ̀mùtí-para.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 21

Wo Deutarónómì 21:20 ni o tọ