Deutarónómì 21:21 BMY

21 Nígbà náà ni gbogbo ọkùnrin ìlú rẹ̀ yóò sọ ọ́ ní òkúta pa. Ìwọ yóò sì mú ìwà ibi kúrò láàrin yín, gbogbo Ísírẹ́lì yóò gbọ́ ẹ̀rù yóò sì bà wọ́n.

Ka pipe ipin Deutarónómì 21

Wo Deutarónómì 21:21 ni o tọ