Deutarónómì 22:1 BMY

1 Bí o bá rí màlúù tàbí àgùntàn arákùnrin rẹ tí ó ń sọnù, má ṣe ṣé àìkíyèsí i rẹ̀ ṣùgbọ́n rí i dájú pé o mú padà wá fún un.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:1 ni o tọ