Deutarónómì 22:2 BMY

2 Bí ọkùnrin náà kì í bá gbé ní tòsí rẹ tàbí bí o kò bá mọ ẹni náà, mú un lọ ilé pẹ̀lú rẹ kí o sì fi pamọ́ títí yóò fi wá a wá. Nígbà náà ni kí o fi fún un.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:2 ni o tọ