Deutarónómì 22:3 BMY

3 Ṣe bákan náà tí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ arákùnrin rẹ tàbí aṣọ ìlekè tàbí ohunkóhun rẹ̀ tí ó sọnù. Má ṣe ṣe àìkíyèsí i rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:3 ni o tọ