Deutarónómì 22:26 BMY

26 Má se fi ohunkóhun ṣe ọmọbìnrin náà; kò ṣẹ ẹ̀ṣẹ̀ tí ó tọ́ sí ikú. Ẹjọ́ yìí rí bí i ti ẹnìkan tí a gbámú tí ó pa aládùúgbò rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:26 ni o tọ