Deutarónómì 22:8 BMY

8 Nígbà tí o bá kọ́ ilé túntún, mọ odi yí òrùlé rẹ̀ ká nítorí kí o má baà mú ẹ̀bi ìtàjẹ̀ sílẹ̀ wá sórí ilẹ̀ rẹ bí ẹnikẹ́ni bá ṣubú láti òrùlé.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:8 ni o tọ