Deutarónómì 22:9 BMY

9 Má ṣe gbin oríṣìí èso méjì sínú ọgbà àjàrà rẹ; bí o bá ṣe bẹ́ẹ̀, kì í ṣe èṣo oko tí o gbìn nìkan ṣùgbọ́n èṣo ọgbà àjàrà pẹ̀lú yóò bàjẹ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:9 ni o tọ