Deutarónómì 24:13 BMY

13 Dá aṣọ ìlékè rẹ padà ní àṣálẹ́ kí ó báà le sùn lórí i rẹ̀. Nígbà náà ni yóò dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, ó sì má a jásí ìwà òdodo níwájú Olúwa Ọlọ́run rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 24

Wo Deutarónómì 24:13 ni o tọ