Deutarónómì 24:14 BMY

14 Má ṣe ni alágbàṣe kan lára tí ó jẹ́ talákà àti aláìní, bóyá ó jẹ́ arákùnrin Isírẹ́lì tàbí àlejò tí ó ń gbé ní ọ̀kan nínú àwọn ìlú rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 24

Wo Deutarónómì 24:14 ni o tọ