Deutarónómì 24:20 BMY

20 Nígbà tí o bá ń gun igi ólífì lára àwọn igi i rẹ, má ṣe padà lọ sí ẹ̀ka náà ní ìgbà kejì. Fi èyí tí ó kù fún àlejò, aláìní baba àti opó.

Ka pipe ipin Deutarónómì 24

Wo Deutarónómì 24:20 ni o tọ