Deutarónómì 24:21 BMY

21 Nígbà tí o bá kórè èṣo àjàrà nínú ọgbà àjàrà rẹ, má ṣe lọ sí ọgbà náà mọ́. Fi èyí tí ó kù fún àlejò, aláìní baba àti opó.

Ka pipe ipin Deutarónómì 24

Wo Deutarónómì 24:21 ni o tọ