Deutarónómì 25:1 BMY

1 Nígbà tí àwọn ènìyàn méjì bá ń jà, kí wọn kó ẹjọ́ lọ sí ilé ìdájọ́, kí àwọn onídàájọ́ dá ẹjọ́ náà, kí wọn dá àre fún aláre àti ẹ̀bi fún ẹlẹ́bi.

Ka pipe ipin Deutarónómì 25

Wo Deutarónómì 25:1 ni o tọ