Deutarónómì 25:2 BMY

2 Bí ó bá tọ́ láti na ẹlẹ́bi, kí onídàájọ́ dá a dọ̀bálẹ̀ kí a sì nà án ní ojú u rẹ̀ ní iye pàsán tí ó tọ́ sí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó sẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 25

Wo Deutarónómì 25:2 ni o tọ