Deutarónómì 25:3 BMY

3 Ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ fún un ju ogójì pàsán lọ. Bí ó bá nà án ju bẹ́ẹ̀ lọ, arákùnrin rẹ̀ yóò di ẹni ìrẹ̀sílẹ̀ ní ojú rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 25

Wo Deutarónómì 25:3 ni o tọ