Deutarónómì 25:17 BMY

17 Rántí ohun tí àwọn ará Ámélékì ṣe sí i yín ní ọ̀nà nígbà tí ẹ̀ ń jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá.

Ka pipe ipin Deutarónómì 25

Wo Deutarónómì 25:17 ni o tọ