Deutarónómì 25:18 BMY

18 Nígbà tí àárẹ̀ mú un yín tí agara sì dá a yín, wọ́n pàdé e yín ní ọ̀nà àjò o yín, wọ́n gé àwọn tí ó rẹ̀yìn kúrò, wọn kò ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Deutarónómì 25

Wo Deutarónómì 25:18 ni o tọ