Deutarónómì 26:15 BMY

15 Wo ilẹ̀ láti ọ̀run wá, ibùgbé mímọ́ rẹ, kí o sì bùkún fún àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì àwọn babańlá wa, ilẹ̀ tí ó ń ṣàn fún wàrà àti fún oyin.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:15 ni o tọ