Deutarónómì 26:16 BMY

16 Olúwa Ọlọ́run rẹ pàṣẹ fún ọ ní òní láti máa tẹ̀lé àwọn ìlànà àti òfin, kí o sì máa ṣe wọ́n pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo àyà rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:16 ni o tọ