Deutarónómì 26:8 BMY

8 Nígbà náà ni Olúwa mú wa jáde wá láti Éjíbítì pẹ̀lu ọwọ́ agbára àti apá nínà, pẹ̀lú ẹ̀rù ńlá àti iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu.

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:8 ni o tọ