Deutarónómì 26:7 BMY

7 Nígbà náà ni a kégbe pe Olúwa Ọlọ́run àwọn baba wa, Olúwa sì gbọ́ ohùn wa, ó sì rí ìrora, làálàá àti ìnira wa.

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:7 ni o tọ