Deutarónómì 26:6 BMY

6 Ṣùgbọ́n àwọn ará Éjíbítì ṣe àìdára sí wa, wọ́n jẹ wá níyà, wọ́n fún wa ní iṣẹ́ líle ṣe.

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:6 ni o tọ