Deutarónómì 27:13 BMY

13 Àwọn ẹ̀yà yìí yóò dúró lórí òkè Ébálì láti gé ègún: Rúbẹ́nì, Gádì, àti Ásérì, àti Ṣébúlúnì, Dánì, àti Náfitanì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 27

Wo Deutarónómì 27:13 ni o tọ