Deutarónómì 29:12 BMY

12 O dúró níhìn ín yìí kí o lè wọ inú májẹ̀mú pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run rẹ, májẹ̀mú tí Olúwa ń ṣe pẹ̀lú ù rẹ lónìí yìí àti tí óun dè pẹ̀lú ìbúra,

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:12 ni o tọ