Deutarónómì 29:13 BMY

13 láti jẹ́wọ́ rẹ lónìí yìí bí ènìyàn an rẹ̀, pé kí ó lè jẹ́ Ọlọ́run rẹ bí ó ti ṣèlérí àti bí ó ti ṣe ìbúra fún àwọn baba à rẹ Ábúráhámù, Ísákì àti Jákọ́bù.

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:13 ni o tọ