Deutarónómì 29:22 BMY

22 Àwọn ọmọ rẹ tí ó tẹ̀lé ìran rẹ lẹ́yìn àti àwọn àlejò tí ó wá láti ilẹ̀ jíjìn yóò rí wàhálà tí ó wá sórí ilẹ̀ àti àwọn àrùn pẹ̀lú tí Olúwa mú bá ọ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:22 ni o tọ