Deutarónómì 29:21 BMY

21 Olúwa yóò sì yọ òun nìkan kúrò nínú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì fún àjálù, gẹ́gẹ́ bí gbogbo ègún májẹ̀mú tí a kọ sí inú ìwé òfin yìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:21 ni o tọ